-
1
Àgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin
Published 2021-12-01“…Bárakú sì ní ọ̀rọ̀ orin láwùjọ ọmọ ènìyàn pàápàá jù lọ àwọn Yorùbá nítorí pé onírúurú ààyè ni orin ti máa ń jẹ jáde nínú ìgbésí-ayé wọn lójoojúmọ́. Bí àwọn akọrin àwùjọ bá sì ń ṣiṣẹ́ ọnà wọn, ìjìnlẹ̀ èdè tó jinná ni wọ́ n fi máa ń gbé e jáde tí yóò sì máa ṣàfihàn bí irú àwọn akọrin bẹ́ ẹ̀ ṣe gbọ́ èdè àti ìmọ̀ nípa àṣà àwùjọ tó ti ń kọrin nítorí pé ìpohùn ìbílẹ̀ èyí tí orin jẹ́ ọ̀ kan pàtàkì lára wọn dà gẹ́gẹ́ bí àwògbè tàbí díńgí tí a fi ń ríran rí àwùjọ. …”
Get full text
Article -
2
Àyẹ ̀wò Ìlò Àpólà- Orúkọ Aṣẹ̀dá Nínú Ìwé Ìtànàròsọ Àjà Ló Lẹrù
Published 2021-12-01“…Lára ọgbọ́n ìwádìí tí a lò ni pé a ka ìwé ìtàn àròsọ Àjà Ló Lẹrù dáadáa, a sì ṣe àfàyọ àwọn OR aṣẹ̀dá jáde nínú rẹ̀. Lẹ́yìn èyí ni a ṣe àkójọpọ̀ àti ìtúpalẹ̀ àwọn OR aṣẹ̀dá wọ̀nyí gẹ́gẹ́ bí ìlànà ìṣẹ̀dá wọn nínú ẹ̀kọ́ mọfọ́lọ́jì. …”
Get full text
Article -
3
Àgbéyẹ̀wò Ipa Èdè, Àṣà, àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá Nínú ọ̀gbagadè Ìtàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Published 2021-12-01“…Bi o tile je pe awon asejoba-amunisin bu enu ate lu ede Yoruba, igbende re ti mu itesiwaju ba imo ero. …”
Get full text
Article